Aipẹ yii ni ọrọ emi lagba, emi ni mo ju ọ, waye laaarin Alaafin Oyo; Oba Abimbola Owoade ati Ooni Ile-Ife; Oba Adeyeye Ogunwusi. Ni bayii, Ataoja Osogbo ati Oluwoo ti ilu Iwo, nipinlẹ Osun ni wọn tun ...
Bi ajijagbara ọmọ Yoruba nni, Sunday Adeyemo (Igboho), ṣe n tẹsiwaju ninu abẹwo rẹ si ọdọ awọn ọba ilẹ Yoruba, ọkunrin to n pe fun idasilẹ orilẹede Yoruba yii ti tu aṣiri miran. Nigba to ṣabẹwo si ...